1 Orin ìgòkè. Ẹ kíyèsi i, ẹ fi ìbùkún fún Olúwa, gbogbo ẹ̀yin ìránṣẹ́ Olúwa, tí ó dúró ní ilé Olúwa ní òru.
Cantique des degrés. Allons! bénissez l’Eternel, vous tous, serviteurs de l’Eternel, qui vous tenez dans la maison du Seigneur durant les nuits.