< Psalms 134 >

1 Orin ìgòkè. Ẹ kíyèsi i, ẹ fi ìbùkún fún Olúwa, gbogbo ẹ̀yin ìránṣẹ́ Olúwa, tí ó dúró ní ilé Olúwa ní òru.
上行之诗。 耶和华的仆人夜间站在耶和华殿中的, 你们当称颂耶和华!
2 Ẹ gbé ọwọ́ yín sókè sí ibi mímọ́, kí ẹ sì fi ìbùkún fún Olúwa.
你们当向圣所举手, 称颂耶和华!
3 Olúwa tí ó dá ọ̀run òun ayé, kí ó bùsi i fún ọ láti Sioni wá.
愿造天地的耶和华, 从锡安赐福给你们!

< Psalms 134 >