< Psalms 117 >

1 Ẹ yin Olúwa, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè; ẹ pòkìkí rẹ̀, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn.
万国啊,你们都当赞美耶和华! 万民哪,你们都当颂赞他!
2 Nítorí ìfẹ́ ńlá rẹ̀ tí ó ní sí wa, àti òtítọ́ Olúwa dúró láéláé. Ẹ yin Olúwa!
因为他向我们大施慈爱; 耶和华的诚实存到永远。 你们要赞美耶和华!

< Psalms 117 >